Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 21:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sunkún síta, kí ó sì pohùnréré ẹ̀kún, ọmọ ènìyàn,nítorí yóò wá sórí àwọn ènìyàn mi;yóò wá sórí gbogbo ọmọ aládé Ísírẹ́lììbẹ̀rù ńlá yóò wá sórí àwọn ènìyàn minítorí idà náà;nítorí náà lu oókan àyà rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 21

Wo Ísíkẹ́lì 21:12 ni o tọ