Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó sọ fún wọn pé: ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Ní ọjọ tí mo yàn Ísírẹ́lì, mo gbé ọwọ́ mi ṣokè nínú ẹ̀jẹ́ sí àwọn ọmọ ilé Jákọ́bù, mo sì fi ara mi hàn wọn ní Éjíbítì, mo gbé ọwọ́ mi sókè nínú ẹ̀jẹ́ wí pé, “Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:5 ni o tọ