Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ní ẹ̀yin yóò mọ̀ pé, Èmi ni Olúwa, nígbà tí mo bá hùwà sí yín nítorí orúkọ mi ni, tí ń kò hùwà sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ibi àti ìwà ìríra yín. Ẹ̀yin Ilé Ísírẹ́lì, ni Olúwa Ọlọ́run wí.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:44 ni o tọ