Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ pé, “Ọmọ ènìyàn, mo ń rán ọ sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, sí ọlọ̀tẹ̀ orílẹ̀ èdè tí wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi; àwọn àti baba ńlá wọn ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi títí di òní-olónìí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 2

Wo Ísíkẹ́lì 2:3 ni o tọ