Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 19:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iná sì jáde láti ọ̀kan lára ẹ̀ka rẹ̀ ó sì pa ẹ̀ka àti èso rẹ̀ run,débi pé kò sí ẹ̀ka tó lágbára lórí rẹ̀ mọ́; èyí to ṣe e fi ṣe ọ̀pá fún olórí mọ́.’Èyí ni orin ọ̀fọ̀ a o sì máa lo bí orin ọ̀fọ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 19

Wo Ísíkẹ́lì 19:14 ni o tọ