Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò yá ènìyàn ni owó ẹ̀dá tàbí kò gba èlétó pọ̀jù. Ó yọ ọwọ́ rẹ̀ kúrò nínúìwà ẹ̀ṣẹ̀, ó sì ń ṣe ìdájọ́ àìṣègbèláàrin ọkùnrin kan àti èkejì rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:8 ni o tọ