Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń fowó ya ni pẹ̀lú èlé ó sì tún ń gba èlé tó pọ̀jù.Ǹjẹ́ irú ọkunrin yìí wa le è yè bí? Kò lè wá láàyè! Nítorí pé ó ti ṣe àwọn ohun ìríra yìí, yóò kú, ẹ̀jẹ̀ rẹ yóò sì wá lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:13 ni o tọ