Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 17:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Èmi fúnra mi yóò mú ọ̀kan lára ẹ̀ka tí ó ga jùlọ lori igi Kédàrí gíga, tí èmi yóò sì gbìn ín, èmi yóò sì gé ọ̀mùnú tí ó sẹ̀sẹ̀ yọ láti òkè, èmi yóò sì gbìn ín sórí òkè tó ga tó sì lókìkí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:22 ni o tọ