Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 17:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n bá pa bùdó ogun tì í, tí wọ́n sì mọ odi láti pa ọ̀pọ̀ ènìyàn, Fáráò pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun àti àjọ ńlá rẹ̀ kò ní lè ṣe ìrànwọ́ fún-un lójú ogun.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:17 ni o tọ