Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 16:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sẹ́ni tó ṣàánú tàbí kẹ́dùn rẹ débi àtiṣe ikankan nínú iwọ́nyi fún ọ ṣùgbọ́n lọ́jọ́ ìbí rẹ, ìta la jù ọ́ sí torí wọ́n kórìíra rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:5 ni o tọ