Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 16:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ ìyà rẹ ni ọ lóòtọ́, to korìíra ọkọ rẹ àti àwọn ọmọ rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ara ilé àwọn arábìnrin rẹ ni ọ nitootọ, àwọn to n korìíra ọkọ wọn sílẹ̀, tó tún ń korìíra àwọn ọmọ. Ará Híítì ni ìyá rẹ, baba rẹ si jẹ́ ara Ámórì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:45 ni o tọ