Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí náà báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Nítorí ọ̀rọ̀ asán àti ìran èké yín, mo lòdì sí yín: ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:8 ni o tọ