Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí èyí, ẹ̀yin kò ní í ríran èké, ẹ̀yin kò sì ní fọ àfọ̀ṣẹ mọ́. Èmi yóò gba àwọn ènìyàn mi lọ́wọ́ yín. Ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:23 ni o tọ