Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ya àwọn ìbòjú yín, láti gba àwọn ènìyàn mi lọ́wọ́ yín, wọn kò sì ní jẹ́ ìjẹ fún yín mọ́. Nígbà náà ni ẹ ó mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:21 ni o tọ