Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn sọtẹ́lẹ̀ lòdì sí àwọn wòlíì Ísírẹ́lì tó ń sọtẹ́lẹ̀, kí o sì sọ fún àwọn tí ń sọtẹ́lẹ̀ láti inú èrò ọkàn wọn: ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa!

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:2 ni o tọ