Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí o sọ pé, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Ègbé ni fún ẹ̀yin obìnrin tí ẹ ń rán ìfúnpá òògùn sí ìgbọ̀nwọ́ àwọn ènìyàn, tí ẹ ń ṣe ìbòjú oríṣìíríṣìí fún orí oníkálukú ènìyàn láti sọdẹ ọkàn wọn: Ẹ̀yin yóò wa dẹkùn fún ọkàn àwọn ènìyàn mi kí ẹ sì pa ọkàn yin mọ́?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:18 ni o tọ