Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Wọ́n ti mú àwọn ènìyàn mi sìnà, wọ́n ní, “Àlàáfíà” nígbà tí kò sí àlàáfíà, nítorí pé bí àwọn ènìyàn bá mọ odi fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ wọn a fi amọ̀ àìpò rẹ́ ẹ, wọn ó sì fi ẹfun kùn ún,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:10 ni o tọ