Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà pé, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí; fún àwọn olùgbé Jérúsálẹ́mù àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì pé: Pẹ̀lú àìbalẹ̀ àyà ni wọn ó máa jẹun wọn, wọn ó sì mu omi pẹ̀lú àìnírètí, kí ilẹ̀ wọn lè di ahoro torí ìwà ipá àwọn tó ń gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:19 ni o tọ