Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa idà ni ẹ ó ṣubú, n ó sì ṣe ìdájọ́ yín ní àwọn ààlà ìlú Ísírẹ́lì. Nígbà náà lẹ ó mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:10 ni o tọ