Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wò, mo sì rí ìjì tó ń jà bọ̀ láti ìhà àríwá ìkùukùu tó nípọn pẹ̀lú mọ̀nàmọ́ná bù yẹ̀rì pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ rokoṣo tó yí i ká. Àárin iná náà rí bí ìgbà tí irin bá ń bẹ nínú iná,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:4 ni o tọ