Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìmọ́lẹ̀ tó yí i ká yìí dàbí ìrísí òṣùmàrè tó yọ nínú ìkuukùu nígbà tí òjò bá rọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìmọ́lẹ̀ tò yí i ká.Báyìí ni ìrísí ògo Olúwa. Nígbà tí mo rí i, mo dojú bolẹ̀, mo sì gbọ́ ohùn ẹnìkan tó ń sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:28 ni o tọ