Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lókè àwọ̀ òfuurufú tó borí wọn yìí ni ohun tí ó ní ìrísí ìtẹ́. Ìtẹ́ náà dàbí òkúta Sáfírè, lókè ní orí ìtẹ́ ní ohun tó dàbí ènìyàn wà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:26 ni o tọ