Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ẹ̀dá náà gbéra, mo gbọ́ ariwo ìyẹ́ wọn tó bolẹ̀ bí i ríru omi, bí i ohùn Olódùmarè, bí i híhó àwọn jagunjagun. Nígbà tí wọ́n dúró jẹ́ẹ́, wọ́n sì rẹ ìyẹ́ wọn sílẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:24 ni o tọ