Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn ẹ̀dá yìí bá ń lọ, kẹ̀kẹ́ náà yóò lọ; bí wọ́n bá dúró jẹ́ẹ́ kẹ̀kẹ́ náà yóò dúró jẹ́ẹ́, bẹ́ẹ̀ sì ni bí àwọn ẹ̀dá yìí bá dìde nílẹ̀, àwọn kẹ̀kẹ́ yìí yóò dìde pẹ̀lú wọn, nítorí pé ẹ̀mí ẹ̀dá alààyè wọ̀nyí wà nínú àwọn kẹ̀kẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:21 ni o tọ