Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpèjúwe àti ìrísí àwọn kẹ̀kẹ́ náà nìyìí: kẹ̀kẹ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rí bákan náà, wọ́n sì ń tàn yinrin yinrin bí i kírísólétì, ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn kẹ̀kẹ́ yìí rí bí i ìgbà tí a fi kẹ̀kẹ́ bọ kẹ̀kẹ́ nínú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:16 ni o tọ