Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrísí àwọn ẹ̀dá alààyè yìí dàbí ẹyin iná tí ń jó tàbí bí i iná tọ́ọ̀sì. Iná tó ń jó ń lọ sókè lọ sódò láàrin àwọn ẹ̀dá alààyè; iná yìí mọ́lẹ̀ rokoṣo, ó sì ń bù yẹ̀rì yẹ̀rì jáde lára rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:13 ni o tọ