Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹrin tí mo di ọmọ ọgbọ̀n ọdún tí mo wà láàrin àwọn ìgbèkùn ní etí òdò Kébárì, àwọn ọ̀run sí sílẹ̀, mo sì rí ìran Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:1 ni o tọ