Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ń rúbọ tí wọ́n yàn fún mi,wọ́n sì ń jẹ ẹran ibẹ̀Ṣùgbọ́n inú Olúwa kò dùn sí wọn.Báyìí yóò rántí ìwà búburú wọnyóò sì jẹ wọ́n níyà fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.Wọn yóò padà sí Éjíbítì

Ka pipe ipin Hósíà 8

Wo Hósíà 8:13 ni o tọ