Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò padà sí ọ̀dọ̀ Ọ̀gá ògo;Wọ́n dàbí ọrun tí ó wà fún ìtànjẹ́Àwọn aṣíwájú wọn yóò ti ipa idà ṣubúnítorí irúnú ahọ́n wọn.Torí èyí, wọn ó fi wọ́n ṣeẹlẹ́yà ní ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Hósíà 7

Wo Hósíà 7:16 ni o tọ