Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ni èmi ó ṣe pẹ̀lú rẹ, Éfúráímù?Kí ni èmi ó ṣe pẹ̀lú rẹ, Júdà?Ìfẹ́ rẹ dàbí ìkùùku òwúrọ̀bí ìrì ìdájí tí ó kọjá lọ kíákíá.

Ka pipe ipin Hósíà 6

Wo Hósíà 6:4 ni o tọ