Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a padà sọ́dọ̀ Olúwaó ti fà wá ya pẹ́rẹpẹ̀rẹṣùgbọ́n yóò mú wa lára dáÓ ti pa wá láraṣùgbọ́n yóò dí ojú ọgbẹ́ wa.

Ka pipe ipin Hósíà 6

Wo Hósíà 6:1 ni o tọ