Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà ti Éfúráímù ri àìsàn rẹ̀,tí Júdà sì rí ojú egbò rẹ̀ni Éfúráímù bá tọ ará Síríà lọ,ó sì ránṣẹ́ sí ọba ńlá náà fún ìrànlọ́wọ́ṣùgbọ́n kò le è wò ó sànbẹ́ẹ̀ ni kò le wo ojú egbò rẹ̀ jinná

Ka pipe ipin Hósíà 5

Wo Hósíà 5:13 ni o tọ