Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 5:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yìn àlùfáà!Ẹ fetí sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì!Ẹ gbọ́, ẹ̀yìn ilé ọba!Ìdájọ́ yìí kàn yín:Ẹ ti jẹ́ ẹ̀bìtì ní MísípàÀwọ̀n ti a nà sìlẹ̀ lórí Tábórì

2. Àwọn ọlọ̀tẹ̀ ti gbilẹ̀ nínú ìpànìyànGbogbo wọn ni èmi ó bá wí,

3. Mo mọ ohun gbogbo nípa ÉfúráímùÍsírẹ́lì kò sì pamọ́ fún miÉfúráímù, ní báyìí ó ti di alágbèrèÍsírẹ́lì sì ti díbàjẹ́

Ka pipe ipin Hósíà 5