Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn mi ń ṣègbé nítorí pé wọn kò ní ìmọ̀“Nítorí pé ẹ ti kọ ìmọ̀ sílẹ̀.Èmi náà kọ̀ yín ní àlùfáà mi;nítorí pé ẹ ti kọ òfìn Ọlọ́run yín sílẹ̀Èmi náà yóò gbàgbé àwọn ọmọ yín.

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:6 ni o tọ