Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 4:16-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe agídíbí alágídí ọmọ màlúùBáwo wá ni Olúwa ṣe fẹ́ bọ́ wọnbí àgùntàn ní pápá oko tútù?

17. Éfúráímù ti darapọ̀ mọ́òrìṣà Ẹ fi sílẹ̀!

18. Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tánwọ́n tún tẹ̀ṣíwájú nínú àgbèrèàwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ.

19. Ìjì ni yóò gbá wọn lọ.Gbogbo ìrúbọ wọn yóò sì kó ìtìjú bá wọn.

Ka pipe ipin Hósíà 4