Lẹ́yìn èyí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò padà láti wá Olúwa Ọlọ́run wọn àti Dáfídì ọba wọn. Wọn yóò sì wá síwájú Olúwa pẹ̀lú ẹ̀rù, wọn ó sì jọ̀wọ́ ara wọn fún Olúwa àti ìbùkún rẹ̀ ní ọjọ́ ìkẹyìn.