Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì sọ fún un pé, “Ìwọ gbọdọ̀ máa gbé pẹ̀lú mi fún ọjọ́ pípẹ́, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe àgbèrè mọ́ tàbí kí o fẹ́ ọkùnrin mìíràn, èmi náà yóò sì gbé pẹ̀lú ù rẹ.”

Ka pipe ipin Hósíà 3

Wo Hósíà 3:3 ni o tọ