Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, èmi yóò mú ọkà mi kúrò nígbà tó bá pọ́n,èmi yóò sì mú wáìnì mi kúrò ní àsìkò rẹ̀.Èmi yóò sì gba ìrun àgùntàn irun àgùtàn àti ọ̀gbọ̀ mi padàmo ti fifun un láti bo ìhòòho rẹ̀.

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:9 ni o tọ