Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sáré lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n kò ní bá wọn;Yóò wá wọn ṣùgbọ́n kò ní rí wọn.Nígbà náà ni yóò sọ pé,‘Èmi ó padà sí ọ̀dọ̀ ọkọ mi àkọ́kọ́nítorí pé ó dára fún mi nígbà náà ju ìsinsìnyí lọ.’

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:7 ni o tọ