Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni èmi yóò ti dá ọgbà àjàrà rẹ̀ padà fún un,Èmi yóò fi àfonífojì Ákórì ṣe ilẹ̀kùn ìrètí fún un.Yóò sì kọrin níbẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbà èwe rẹ̀gẹ́gẹ́ bí ìgbà tó kúrò ní Éjíbítì

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:15 ni o tọ