Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò pa àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀ run,Èyí tí ó pè ní èrèe rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn Olólùfẹ́ rẹ̀,Èmi yóò sọ wọ́n di igbó,àwọn ẹranko búburú yóò sì jẹ́ wọn run.

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:12 ni o tọ