Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà wọn yóò dàbí ìkùùkù òwúrọ̀,bí ìrì òwúrọ̀ kùtùkùtù tó máa ń parẹ́,bí i èèpo ọkà tí afẹ́fẹ́ gbé láti ibi ìpakàbí èéfín tó rú jáde gba ojú fèrèsé.

Ka pipe ipin Hósíà 13

Wo Hósíà 13:3 ni o tọ