Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 13:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Bí ó tilẹ̀ gbilẹ̀ láàrin àwọn arákùnrin rẹ̀afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn láti ọ̀dọ̀ Olúwa yóò wá,Yóò fẹ́ wá láti inú asálẹ̀orísun omi rẹ̀ yóò gbẹkànga rẹ̀ yóò gbẹpẹ̀lú olè yóò fọ́ ilé ẹrùàti gbogbo ilé ìṣúra rẹ̀

16. Ará Sámáríà gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn,nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí Ọlọ́run wọn.Wọn ó ti ipa idà ṣubú;a ó fọ́ àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀,A ó sì la àwọn aboyún wọn nínú.”

Ka pipe ipin Hósíà 13