Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 12:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Jákọ́bù sá lọ si orílẹ̀ èdè Árámù;Ísírẹ́lì sìn kí o tó fẹ ìyàwóó ṣe ìtọjú ẹran láti fi san owó ìyàwó.

13. Olúwa lo wòlíì kan láti mú Ísírẹ́lì jáde wá láti Éjíbítì,nípaṣẹ̀ wòlíì kan ó ṣe ìtọ́jú rẹ̀.

14. Ṣùgbọ́n Éfúráímù ti mú un bínú gidigidi; Olúwa rẹ̀ yóò sì fi ẹ̀bi ìtàjẹ̀sílẹ̀ sí orí rẹ̀òun yóò sì san án padà fún un nítorí ìwà ẹ̀gàn an rẹ̀.

Ka pipe ipin Hósíà 12