Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 12:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Éfúráímù ń jẹ afẹ́fẹ́;Ó n lépa afẹ́fẹ́ ìwọ̀ oòrùn ní gbogbo ọjọ́.Ó sì ń gbèrú nínú irọ́Ó dá májẹ̀mú pẹ̀lú ÁsíríàÓ si fi òróró ólífì ránsẹ́ sí Éjíbítì.

2. Olúwa ní ẹ̀sùn tí yóò fí kan Júdàyóò fìyà jẹ Jákọ́bù gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀yóò sì sán fún-un gẹ́gẹ́ bí i ìṣe rẹ̀.

3. Láti inú oyun ni ó ti di arákùnrin rẹ̀ mú ni gìgísẹ̀,àti nípa ìpá rẹ̀ ó ni agbára pẹ̀lú Ọlọ́run

Ka pipe ipin Hósíà 12