Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hágáì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Ògo ìkẹyìn àwọn ọmọ-ogun ilé yìí yóò pọ̀ ju ti ìṣáájú lọ;’ ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí: ‘Àti ní ìhín yìí ni Èmi ó sì fi àlàáfíà fún ni’, ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.”

Ka pipe ipin Hágáì 2

Wo Hágáì 2:9 ni o tọ