Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hágáì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Hágáì dáhùn ó sì wí pé, “ ‘Bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn wọ̀nyí rí, bẹ́ẹ̀ sì ni orílẹ̀-èdè yìí rí níwájú mi,’ ni Olúwa wí. ‘Bẹ́ẹ̀ sì ni olukuluku iṣẹ́ ọwọ́ wọn; èyí tí wọ́n sì fi rúbọ níbẹ̀ jẹ́ aláìmọ́.

Ka pipe ipin Hágáì 2

Wo Hágáì 2:14 ni o tọ