Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hágáì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sérúbábélì ọmọ Séítíélì, Jósúà ọmọ Jósédékì, olórí àlùfáà pẹ̀lú gbogbo ènìyàn ìyókù, gba ohùn Olúwa Ọlọ́run wọn gbọ́ àti ọ̀rọ̀ wòlíì Hágáì, nítorí Olúwa Ọlọ́run ni ó rán an. Àwọn ènìyàn sì bẹ̀rù Olúwa.

Ka pipe ipin Hágáì 1

Wo Hágáì 1:12 ni o tọ