Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa mo tí gbọ́ ohùn rẹ;ẹrú sì ba mi fún iṣẹ́ rẹ Olúwaṣọ wọn di ọ̀tún ní ọjọ́ ti wa,ní àkókò tiwa, jẹ́ kó di mímọ̀;ni ìbínú, rántí àánú.

Ka pipe ipin Hábákúkù 3

Wo Hábákúkù 3:2 ni o tọ