Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí igi ọ̀pọ̀tọ́ ko tilẹ̀ tanná,tí èso kò sí nínú àjàrà;tí iṣẹ igi olifi yóò jẹ́ àṣedànù,àwọn oko ki yóò sì mú oúnjẹ wá;tí a ṣi ke agbo ẹran kúrò nínú agbo,tí ki yóò sì sí ọwọ́ ẹran ni ibùsọ̀ mọ́,

Ka pipe ipin Hábákúkù 3

Wo Hábákúkù 3:17 ni o tọ